1 Kronika 4:18
1 Chronicles 4:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Aya rẹ̀ láti ẹ̀yà Juda sì bí Jaredi baba Gedori, àti Heberi baba Soko àti Jekutieli baba Sanoa. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọbìnrin Farao Bitia, ẹni ti Meredi ti fẹ́.
1 Chronicles 4:18 in English
1 Chronicles 4:18 · Berean Standard Bible
These were the children of Pharaoh’s daughter Bithiah.* Mered also took a Judean * wife, who gave birth to Jered the father of Gedor, Heber the father of Soco, and Jekuthiel the father of Zanoah.
Context
16Àwọn ọmọ Jehaleeli:
Sifi, àti Sifa, Tiria àti Asareeli. 17Àwọn ọmọ Esra:
Jeteri, Meredi, Eferi àti Jaloni.
Ọ̀kan lára àwọn aya Meredi sì bí Miriamu, Ṣammai àti Iṣba baba Eṣitemoa. 18Aya rẹ̀ láti ẹ̀yà Juda sì bí Jaredi baba Gedori, àti Heberi baba Soko àti Jekutieli baba Sanoa. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ ọmọbìnrin Farao Bitia, ẹni ti Meredi ti fẹ́. 19Àwọn ọmọ aya Hodiah arábìnrin Nahamu,
baba Keila ará Garimu, àti Eṣitemoa àwọn ará Maakati. 20Àwọn ọmọ Ṣimoni:
Amnoni, Rina, Beni-Hanani àti Tiloni.
Àwọn ọmọ Iṣi:
Soheti àti Beni-Soheti.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.