1 Kronika 24:7
1 Chronicles 24:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìpín èkínní jáde sí Jehoiaribu, èkejì sí Jedaiah,
1 Chronicles 24:7 in English
1 Chronicles 24:7 · Berean Standard Bible
The first lot fell to Jehoiarib, the second to Jedaiah,
Context
5Wọ́n sì pín wọn láìṣègbè nípa yíya ìpín, nítorí àwọn olórí ibi mímọ́ àti àwọn olórí ilé Ọlọ́run wà láàrín àwọn ọmọ méjèèjì Eleasari àti Itamari. 6Ṣemaiah ọmọ Netaneli, akọ̀wé ọ̀kan lára àwọn ọmọ Lefi sì kọ orúkọ wọn níwájú ọba àti àwọn ìjòyè: Sadoku àlùfáà, Ahimeleki ọmọ Abiatari àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà tí a mú láti ọ̀dọ̀ Eleasari àti ọ̀kan láti ọ̀dọ̀ Itamari. 7Ìpín èkínní jáde sí Jehoiaribu,
èkejì sí Jedaiah, 8ẹlẹ́ẹ̀kẹta sì ni Harimu,
ẹ̀kẹrin sì ní Seorimu, 9ẹ̀karùnún sì ni Malkiah,
ẹlẹ́ẹ̀kẹfà sì ni Mijamini,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.