1 Kronika 24:8
1 Chronicles 24:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ẹlẹ́ẹ̀kẹta sì ni Harimu, ẹ̀kẹrin sì ní Seorimu,
1 Chronicles 24:8 in English
1 Chronicles 24:8 · Berean Standard Bible
the third to Harim, the fourth to Seorim,
Context
6Ṣemaiah ọmọ Netaneli, akọ̀wé ọ̀kan lára àwọn ọmọ Lefi sì kọ orúkọ wọn níwájú ọba àti àwọn ìjòyè: Sadoku àlùfáà, Ahimeleki ọmọ Abiatari àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà tí a mú láti ọ̀dọ̀ Eleasari àti ọ̀kan láti ọ̀dọ̀ Itamari. 7Ìpín èkínní jáde sí Jehoiaribu,
èkejì sí Jedaiah, 8ẹlẹ́ẹ̀kẹta sì ni Harimu,
ẹ̀kẹrin sì ní Seorimu, 9ẹ̀karùnún sì ni Malkiah,
ẹlẹ́ẹ̀kẹfà sì ni Mijamini, 10èkeje sì ni Hakosi,
ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ sí ni Abijah,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.