1 Kronika 16:27
1 Chronicles 16:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Dídán àti ọláńlá ni ó wà níwájú rẹ̀; agbára àti ayọ̀ ni ó wà ní ibi ibùgbé rẹ̀.
1 Chronicles 16:27 in English
1 Chronicles 16:27 · Berean Standard Bible
Splendor and majesty are before Him; strength and joy fill His dwelling.
Context
25Nítorí títóbi ni Olúwa òun sì ni ìyìn yẹ jùlọ;
òun ni kí a bẹ̀rù ju gbogbo àwọn Ọlọ́run lọ. 26Nítorí gbogbo àwọn ọlọ́run orílẹ̀-èdè jẹ́ àwọn òrìṣà,
ṣùgbọ́n Olúwa dá àwọn ọ̀run. 27Dídán àti ọláńlá ni ó wà níwájú rẹ̀;
agbára àti ayọ̀ ni ó wà ní ibi ibùgbé rẹ̀. 28Fi fún Olúwa, ẹ̀yin ìdílé àwọn orílẹ̀-èdè,
ẹ fi ògo àti ipá fún Olúwa. 29Fún Olúwa ní ìyìn nítorí orúkọ rẹ̀;
gbé ọrẹ kí ẹ sì wá síwájú rẹ̀.
Sìn Olúwa nínú inú dídùn ìwà mímọ́ rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.