1 Kronika 16:26
1 Chronicles 16:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí gbogbo àwọn ọlọ́run orílẹ̀-èdè jẹ́ àwọn òrìṣà, ṣùgbọ́n Olúwa dá àwọn ọ̀run.
1 Chronicles 16:26 in English
1 Chronicles 16:26 · Berean Standard Bible
For all the gods of the nations are idols, but it is the LORD who made the heavens.
Context
24Kéde ògo à rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè,
ohun ìyàlẹ́nu tí ó ṣe láàrín gbogbo ènìyàn. 25Nítorí títóbi ni Olúwa òun sì ni ìyìn yẹ jùlọ;
òun ni kí a bẹ̀rù ju gbogbo àwọn Ọlọ́run lọ. 26Nítorí gbogbo àwọn ọlọ́run orílẹ̀-èdè jẹ́ àwọn òrìṣà,
ṣùgbọ́n Olúwa dá àwọn ọ̀run. 27Dídán àti ọláńlá ni ó wà níwájú rẹ̀;
agbára àti ayọ̀ ni ó wà ní ibi ibùgbé rẹ̀. 28Fi fún Olúwa, ẹ̀yin ìdílé àwọn orílẹ̀-èdè,
ẹ fi ògo àti ipá fún Olúwa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.