1 Kronika 16:25
1 Chronicles 16:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí títóbi ni Olúwa òun sì ni ìyìn yẹ jùlọ; òun ni kí a bẹ̀rù ju gbogbo àwọn Ọlọ́run lọ.
1 Chronicles 16:25 in English
1 Chronicles 16:25 · Berean Standard Bible
For great is the LORD, and greatly to be praised; He is to be feared above all gods.
Context
23Kọrin sí Olúwa gbogbo ayé;
ẹ máa fi ìgbàlà rẹ̀ hàn láti ọjọ́ dé ọjọ́. 24Kéde ògo à rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè,
ohun ìyàlẹ́nu tí ó ṣe láàrín gbogbo ènìyàn. 25Nítorí títóbi ni Olúwa òun sì ni ìyìn yẹ jùlọ;
òun ni kí a bẹ̀rù ju gbogbo àwọn Ọlọ́run lọ. 26Nítorí gbogbo àwọn ọlọ́run orílẹ̀-èdè jẹ́ àwọn òrìṣà,
ṣùgbọ́n Olúwa dá àwọn ọ̀run. 27Dídán àti ọláńlá ni ó wà níwájú rẹ̀;
agbára àti ayọ̀ ni ó wà ní ibi ibùgbé rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.