1 Kronika 16:23
1 Chronicles 16:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kọrin sí Olúwa gbogbo ayé; ẹ máa fi ìgbàlà rẹ̀ hàn láti ọjọ́ dé ọjọ́.
1 Chronicles 16:23 in English
1 Chronicles 16:23 · Berean Standard Bible
Sing to the LORD, all the earth. Proclaim His salvation day after day.
Context
21Kò gba ọkùnrin kankan láyè láti pọ́n wọn lójú;
nítorí tiwọn, ó bá àwọn ọba wí. 22“Má ṣe fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi;
má ṣe pa àwọn wòlíì mi lára.” 23Kọrin sí Olúwa gbogbo ayé;
ẹ máa fi ìgbàlà rẹ̀ hàn láti ọjọ́ dé ọjọ́. 24Kéde ògo à rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè,
ohun ìyàlẹ́nu tí ó ṣe láàrín gbogbo ènìyàn. 25Nítorí títóbi ni Olúwa òun sì ni ìyìn yẹ jùlọ;
òun ni kí a bẹ̀rù ju gbogbo àwọn Ọlọ́run lọ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.