1 Kronika 16:22
1 Chronicles 16:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Má ṣe fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi; má ṣe pa àwọn wòlíì mi lára.”
1 Chronicles 16:22 in English
1 Chronicles 16:22 · Berean Standard Bible
‘Do not touch My anointed ones! Do no harm to My prophets!’
Context
20wọ́n rìn kiri láti orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè
láti ìjọba kan sí èkejì. 21Kò gba ọkùnrin kankan láyè láti pọ́n wọn lójú;
nítorí tiwọn, ó bá àwọn ọba wí. 22“Má ṣe fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi;
má ṣe pa àwọn wòlíì mi lára.” 23Kọrin sí Olúwa gbogbo ayé;
ẹ máa fi ìgbàlà rẹ̀ hàn láti ọjọ́ dé ọjọ́. 24Kéde ògo à rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè,
ohun ìyàlẹ́nu tí ó ṣe láàrín gbogbo ènìyàn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.