1 Kronika 16:20
1 Chronicles 16:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
wọ́n rìn kiri láti orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè láti ìjọba kan sí èkejì.
1 Chronicles 16:20 in English
1 Chronicles 16:20 · Berean Standard Bible
they wandered from nation to nation, from one kingdom to another.
Context
18“Sí ọ, ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ Kenaani.
Gẹ́gẹ́ bí ààyè tí ìwọ yóò jogún.” 19Nígbà tí wọn kéré ní iye,
wọ́n kéré gidigidi, wọ́n sì jẹ́ àlejò níbẹ̀, 20wọ́n rìn kiri láti orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè
láti ìjọba kan sí èkejì. 21Kò gba ọkùnrin kankan láyè láti pọ́n wọn lójú;
nítorí tiwọn, ó bá àwọn ọba wí. 22“Má ṣe fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi;
má ṣe pa àwọn wòlíì mi lára.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.