1 Kronika 11:26
1 Chronicles 11:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn akọni ọkùnrin náà nìyí: Asaheli arákùnrin Joabu, Elhanani ọmọ Dodo láti Bẹtilẹhẹmu,
1 Chronicles 11:26 in English
1 Chronicles 11:26 · Berean Standard Bible
Now these were the mighty men: Asahel the brother of Joab, Elhanan son of Dodo of Bethlehem,
Context
24Nǹkan wọ̀nyí sì ní ìwà akin Benaiah ọmọ Jehoiada; ohun náà pẹ̀lú sì di olókìkí gẹ́gẹ́ bí àwọn akọni ọkùnrin mẹ́ta. 25Ó sì ní ọlá púpọ̀ ju àwọn ọgbọ̀n lọ, ṣùgbọ́n a kò kà á láàrín àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta. Dafidi sì fi sí ìkáwọ́ àwọn ẹ̀ṣọ́. 26Àwọn akọni ọkùnrin náà nìyí:
Asaheli arákùnrin Joabu,
Elhanani ọmọ Dodo láti Bẹtilẹhẹmu, 27Ṣamotu ará Harori,
Helesi ará Peloni 28Ira ọmọ Ikẹsi láti Tekoa,
Abieseri láti Anatoti,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.