Native Bible

1 Chronicles 11:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣamotu ará Harori, Helesi ará Peloni

1 Chronicles 11:27 in English

1 Chronicles 11:27 · Berean Standard Bible

Shammoth the Harorite,* Helez the Pelonite,

Context

25Ó sì ní ọlá púpọ̀ ju àwọn ọgbọ̀n lọ, ṣùgbọ́n a kò kà á láàrín àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta. Dafidi sì fi sí ìkáwọ́ àwọn ẹ̀ṣọ́. 26Àwọn akọni ọkùnrin náà nìyí: Asaheli arákùnrin Joabu, Elhanani ọmọ Dodo láti Bẹtilẹhẹmu, 27Ṣamotu ará Harori, Helesi ará Peloni 28Ira ọmọ Ikẹsi láti Tekoa, Abieseri láti Anatoti, 29Sibekai ará Huṣati, láti ará Ahohi

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.