Native Bible

Zechariah 8:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọ̀rọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun si tún tọ́ mí wá.

Zechariah 8:1 in English

Zechariah 8:1 · Berean Standard Bible

Again the word of the LORD of Hosts came to me, saying:

Context

1Ọ̀rọ̀ Olúwa àwọn ọmọ-ogun si tún tọ́ mí wá. 2Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí, “Owú ńlá ńlá ni mo jẹ fún Sioni, pẹ̀lú ìbínú ńlá ńlá ni mo fi jowú fún un.” 3Báyìí ni Olúwa wí, “Mo yípadà sí Sioni èmi ó sì gbé àárín Jerusalẹmu. Nígbà náà ni a ó sì pé Jerusalẹmu ni ìlú ńlá òtítọ́; àti òkè ńlá Olúwa àwọn ọmọ-ogun, ni a ó pè ní òkè ńlá mímọ́.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.