Titu 3:15
Titus 3:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbogbo àwọn tí ń bẹ lọ́dọ̀ mi kí ọ. Bá mi kí àwọn tí ó fẹ́ wa nínú ìgbàgbọ́. Kí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú gbogbo yín.
Titus 3:15 in English
Titus 3:15 · Berean Standard Bible
All who are with me send you greetings. Greet those who love us in the faith. Grace be with all of you.*
Context
13Sa gbogbo agbára rẹ láti ran Senasi amòfin àti Apollo lọ́wọ́ nínú ìrìnàjò wọn. Rí i dájú pé wọ́n ní ohun gbogbo tí wọn nílò. 14Àwọn ènìyàn nílò láti kọ́ bí a tí ń fi ara ẹni jì sí iṣẹ́ rere kí wọn ba à le pèsè ohun kòsémánìí fún ara wọn, nípa èyí, wọn kì yóò jẹ́ aláìléso. 15Gbogbo àwọn tí ń bẹ lọ́dọ̀ mi kí ọ.
Bá mi kí àwọn tí ó fẹ́ wa nínú ìgbàgbọ́.
Kí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú gbogbo yín.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.