Orin Solomoni 6:13
Song of Songs 6:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Padà wá, padà wá, ìwọ ọmọ Ṣulamati; padà wá, padà wá, kí àwa kí ó lè yọ́ ọ wò.
Song of Songs 6:13 in English
Song of Songs 6:13 · Berean Standard Bible
Come back, come back, O Shulammite! Come back, come back, that we may gaze upon you.
Context
11Èmi sọ̀kalẹ̀ lọ sí ibi ọgbà èso igi
láti wo àwọn ẹ̀ka igi tuntun ní àfonífojì,
láti rí i bí àjàrà rúwé,
tàbí bí pomegiranate ti rudi. 12Kí èmi tó mọ̀,
àárẹ̀ ọkàn mú mi, mo sì fẹ́ kí ń wà láàrín àwọn ènìyàn mi. 13Padà wá, padà wá, ìwọ ọmọ Ṣulamati;
padà wá, padà wá, kí àwa kí ó lè yọ́ ọ wò. 14(13) Èéṣe tí ẹ̀yin fẹ́ yọ́ Ṣulamati wò,
bí ẹni pé orin ijó Mahanaimu?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.