Romu 3:18
Romans 3:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Ìbẹ̀rù Ọlọ́run kò sí níwájú wọn.”
Romans 3:18 in English
Romans 3:18 · Berean Standard Bible
“There is no fear of God before their eyes.”*
Context
16ìparun àti ìpọ́njú wà lọ́nà wọn. 17Ọ̀nà àlàáfíà ni wọn kò sì mọ̀,” 18“Ìbẹ̀rù Ọlọ́run kò sí níwájú wọn.” 19Àwa sì mọ̀ pé ohunkóhun tí òfin bá wí, ó ń wí fún àwọn tí ó wà lábẹ́ òfin: kí gbogbo ẹnu bá à lè dákẹ́ àti kí a lè mú gbogbo aráyé wá sábẹ́ ìdájọ́ Ọlọ́run. 20Nítorí pé nípa iṣẹ́ òfin, a kì yóò dá ẹnikẹ́ni láre níwájú rẹ̀: nítorí nípa òfin ni ìmọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ ti wá.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.