Native Bible

Romans 3:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọ̀nà àlàáfíà ni wọn kò sì mọ̀,”

Romans 3:17 in English

Romans 3:17 · Berean Standard Bible

and the way of peace they have not known.”*

Context

15“Ẹsẹ̀ wọn yára láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀, 16ìparun àti ìpọ́njú wà lọ́nà wọn. 17Ọ̀nà àlàáfíà ni wọn kò sì mọ̀,” 18“Ìbẹ̀rù Ọlọ́run kò sí níwájú wọn.” 19Àwa sì mọ̀ pé ohunkóhun tí òfin bá wí, ó ń wí fún àwọn tí ó wà lábẹ́ òfin: kí gbogbo ẹnu bá à lè dákẹ́ àti kí a lè mú gbogbo aráyé wá sábẹ́ ìdájọ́ Ọlọ́run.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.