Romu 11:35
Romans 11:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Tàbí ta ni ó kọ́ fi fún un, tí a kò sì san padà fún un?”
Romans 11:35 in English
Romans 11:35 · Berean Standard Bible
“Who has first given to God, that God should repay him?”*
Context
33A! Ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ àti ọgbọ́n àti ìmọ̀ Ọlọ́run!
Àwámárídìí ìdájọ́ rẹ̀ ti rí,
ọ̀nà rẹ̀ sì jù àwárí lọ! 34“Nítorí ta ni ó mọ ọkàn Olúwa?
Tàbí ta ni í ṣe ìgbìmọ̀ rẹ̀?” 35“Tàbí ta ni ó kọ́ fi fún un,
tí a kò sì san padà fún un?” 36Nítorí láti ọ̀dọ̀ rẹ̀, àti nípa rẹ̀, àti fún un ni ohun gbogbo;
ẹni tí ògo wà fún láéláé! Àmín.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.