Native Bible

Romans 11:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí láti ọ̀dọ̀ rẹ̀, àti nípa rẹ̀, àti fún un ni ohun gbogbo; ẹni tí ògo wà fún láéláé! Àmín.

Romans 11:36 in English

Romans 11:36 · Berean Standard Bible

For from Him and through Him and to Him are all things. To Him be the glory forever! Amen.

Context

34“Nítorí ta ni ó mọ ọkàn Olúwa? Tàbí ta ni í ṣe ìgbìmọ̀ rẹ̀?” 35“Tàbí ta ni ó kọ́ fi fún un, tí a kò sì san padà fún un?” 36Nítorí láti ọ̀dọ̀ rẹ̀, àti nípa rẹ̀, àti fún un ni ohun gbogbo; ẹni tí ògo wà fún láéláé! Àmín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.