Saamu 94:6
Psalms 94:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n pa àwọn opó àti àlejò, wọ́n sì pa àwọn ọmọ aláìní baba.
Psalms 94:6 in English
Psalms 94:6 · Berean Standard Bible
They kill the widow and the foreigner; they murder the fatherless.
Context
4Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga jáde;
gbogbo àwọn olùṣe búburú
kún fún ìṣògo. 5Wọ́n fọ́ àwọn ènìyàn rẹ túútúú, Olúwa:
wọ́n pọ́n ilẹ̀ ìní rẹ̀ lójú. 6Wọ́n pa àwọn opó àti àlejò,
wọ́n sì pa àwọn ọmọ aláìní baba. 7Wọ́n sọ pé, “Olúwa kò rí i;
Ọlọ́run Jakọbu kò sì kíyèsi i.” 8Kíyèsi i, ẹ̀yin aláìlóye nínú àwọn ènìyàn;
ẹ̀yin aṣiwèrè, nígbà wo ni ẹ̀yin yóò lóye?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.