Saamu 94:8
Psalms 94:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kíyèsi i, ẹ̀yin aláìlóye nínú àwọn ènìyàn; ẹ̀yin aṣiwèrè, nígbà wo ni ẹ̀yin yóò lóye?
Psalms 94:8 in English
Psalms 94:8 · Berean Standard Bible
Take notice, O senseless among the people! O fools, when will you be wise?
Context
6Wọ́n pa àwọn opó àti àlejò,
wọ́n sì pa àwọn ọmọ aláìní baba. 7Wọ́n sọ pé, “Olúwa kò rí i;
Ọlọ́run Jakọbu kò sì kíyèsi i.” 8Kíyèsi i, ẹ̀yin aláìlóye nínú àwọn ènìyàn;
ẹ̀yin aṣiwèrè, nígbà wo ni ẹ̀yin yóò lóye? 9Ẹni tí ó gbin etí, ó lè ṣe aláìgbọ́ bí?
Ẹni tí ó dá ojú?
Ó ha lè ṣe aláìríran bí? 10Ẹni tí ń bá orílẹ̀-èdè wí, ṣé kò lè tọ́ ni ṣọ́nà bí?
Ẹni tí ń kọ́ ènìyàn ha lè ṣàìní ìmọ̀ bí?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.