Saamu 94:12
Psalms 94:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ìwọ bá wí, Olúwa, ẹni tí ìwọ kọ́ nínú òfin rẹ,
Psalms 94:12 in English
Psalms 94:12 · Berean Standard Bible
Blessed is the man You discipline, O LORD, and teach from Your law,
Context
10Ẹni tí ń bá orílẹ̀-èdè wí, ṣé kò lè tọ́ ni ṣọ́nà bí?
Ẹni tí ń kọ́ ènìyàn ha lè ṣàìní ìmọ̀ bí? 11Olúwa mọ èrò inú ènìyàn;
ó mọ̀ pé asán ni wọ́n. 12Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí
ìwọ bá wí, Olúwa,
ẹni tí ìwọ kọ́ nínú òfin rẹ, 13Ìwọ gbà á kúrò nínú ọjọ́ ibi,
títí a ó fi wa ihò sílẹ̀ fún ẹni búburú. 14Nítorí Olúwa kò ní kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀,
Òun kò sì ní kọ ilẹ̀ ìní rẹ̀ sílẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.