Saamu 94:11
Psalms 94:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Olúwa mọ èrò inú ènìyàn; ó mọ̀ pé asán ni wọ́n.
Psalms 94:11 in English
Psalms 94:11 · Berean Standard Bible
The LORD knows the thoughts of man, that they are futile.*
Context
9Ẹni tí ó gbin etí, ó lè ṣe aláìgbọ́ bí?
Ẹni tí ó dá ojú?
Ó ha lè ṣe aláìríran bí? 10Ẹni tí ń bá orílẹ̀-èdè wí, ṣé kò lè tọ́ ni ṣọ́nà bí?
Ẹni tí ń kọ́ ènìyàn ha lè ṣàìní ìmọ̀ bí? 11Olúwa mọ èrò inú ènìyàn;
ó mọ̀ pé asán ni wọ́n. 12Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí
ìwọ bá wí, Olúwa,
ẹni tí ìwọ kọ́ nínú òfin rẹ, 13Ìwọ gbà á kúrò nínú ọjọ́ ibi,
títí a ó fi wa ihò sílẹ̀ fún ẹni búburú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.