Saamu 92:6
Psalms 92:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òpè ènìyàn kò mọ̀ ọ́n, aṣiwèrè kò sì mọ̀ ọ́n,
Psalms 92:6 in English
Psalms 92:6 · Berean Standard Bible
A senseless man does not know, and a fool does not understand,
Context
4Nítorí ìwọ ni ó mú inú mi dùn
nípa iṣẹ́ rẹ Olúwa;
èmi kọrin ayọ̀ sí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. 5Báwo ni iṣẹ́ rẹ tí tóbi tó, Olúwa?
Èrò inú rẹ ìjìnlẹ̀ ni! 6Òpè ènìyàn kò mọ̀ ọ́n,
aṣiwèrè kò sì mọ̀ ọ́n, 7nígbà tí àwọn ènìyàn búburú bá rú jáde bí i koríko
àti gbogbo àwọn olùṣe búburú gbèrú,
wọn yóò run láéláé. 8Ṣùgbọ́n ìwọ Olúwa ni a ó gbéga títí láé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.