Native Bible

Psalms 8:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa, Olúwa wa, orúkọ rẹ ti ní ìyìn tó ní gbogbo ayé!

Psalms 8:9 in English

Psalms 8:9 · Berean Standard Bible

O LORD, our Lord, how majestic is Your name in all the earth!

Context

7àwọn agbo àgùntàn àti àwọn màlúù, àti ẹranko igbó, 8ẹyẹ ojú ọrun, àti ẹja inú Òkun, àti ohun tí ń wẹ nínú ipa Òkun. 9Olúwa, Olúwa wa, orúkọ rẹ ti ní ìyìn tó ní gbogbo ayé!

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.