Saamu 8:7
Psalms 8:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
àwọn agbo àgùntàn àti àwọn màlúù, àti ẹranko igbó,
Psalms 8:7 in English
Psalms 8:7 · Berean Standard Bible
all sheep and oxen, and even the beasts of the field,
Context
5Ìwọ ṣe é ní onírẹ̀lẹ̀ díẹ̀ ju Ọlọ́run lọ,
ìwọ sì dé e ní adé ògo àti ọlá. 6Ìwọ mú un jẹ ọba lórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ;
ìwọ sì fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀: 7àwọn agbo àgùntàn àti àwọn màlúù,
àti ẹranko igbó, 8ẹyẹ ojú ọrun,
àti ẹja inú Òkun,
àti ohun tí ń wẹ nínú ipa Òkun. 9Olúwa, Olúwa wa,
orúkọ rẹ ti ní ìyìn tó ní gbogbo ayé!
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.