Saamu 78:33
Psalms 78:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
O fi òpin sí ayé wọn nínú asán àti ọdún wọn nínú ìpayà.
Psalms 78:33 in English
Psalms 78:33 · Berean Standard Bible
So He ended their days in futility,* and their years in sudden terror.
Context
31ìbínú Ọlọ́run dìde sí wọn
ó pa àwọn tí ó jùlọ nínú wọn,
ó sì lu àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin Israẹli bolẹ̀. 32Nínú gbogbo ìwọ̀nyí, wọ́n ń dẹ́ṣẹ̀ síwájú;
nínú gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀, wọ́n kò gbàgbọ́. 33O fi òpin sí ayé wọn nínú asán
àti ọdún wọn nínú ìpayà. 34Nígbàkígbà tí Ọlọ́run bá pa wọ́n,
wọn yóò wá a kiri;
wọn yóò fi ìtara yípadà sí i. 35Wọ́n rántí pé Ọlọ́run ní àpáta wọn;
wí pé Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo jùlọ ni olùràpadà àpáta wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.