Saamu 73:12
Psalms 73:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bí àwọn ènìyàn búburú ṣe rí nìyí, ènìyàn asán, wọ́n ń pọ̀ ní ọrọ̀.
Psalms 73:12 in English
Psalms 73:12 · Berean Standard Bible
Behold, these are the wicked— always carefree as they increase their wealth.
Context
10Nítorí náà àwọn ènìyàn wọn yípadà sí wọn
wọ́n sì mu omi ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. 11Wọ́n wí pé, “Báwo ni Ọlọ́run yóò ṣe mọ̀?
Ọ̀gá-ògo ha ní ìmọ̀ bí?” 12Bí àwọn ènìyàn búburú ṣe rí nìyí,
ènìyàn asán, wọ́n ń pọ̀ ní ọrọ̀. 13Nítòótọ́ nínú asán ni mo pa ọkàn mi mọ́;
nínú asán ni mo wẹ ọwọ́ mi ní àìlẹ́ṣẹ̀. 14Ní gbogbo ọjọ́ ni a ń yọ mí lẹ́nu;
a sì ń jẹ mí ní yà ní gbogbo òwúrọ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.