Saamu 73:11
Psalms 73:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n wí pé, “Báwo ni Ọlọ́run yóò ṣe mọ̀? Ọ̀gá-ògo ha ní ìmọ̀ bí?”
Psalms 73:11 in English
Psalms 73:11 · Berean Standard Bible
The wicked say, “How can God know? Does the Most High have knowledge?”
Context
9Wọ́n ń gbé ẹ̀mí wọn lé ọ̀run
ahọ́n wọn gba ipò ayé. 10Nítorí náà àwọn ènìyàn wọn yípadà sí wọn
wọ́n sì mu omi ní ọ̀pọ̀lọpọ̀. 11Wọ́n wí pé, “Báwo ni Ọlọ́run yóò ṣe mọ̀?
Ọ̀gá-ògo ha ní ìmọ̀ bí?” 12Bí àwọn ènìyàn búburú ṣe rí nìyí,
ènìyàn asán, wọ́n ń pọ̀ ní ọrọ̀. 13Nítòótọ́ nínú asán ni mo pa ọkàn mi mọ́;
nínú asán ni mo wẹ ọwọ́ mi ní àìlẹ́ṣẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.