Native Bible

Psalms 61:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti òpin ayé wá ni èmi yóò pè ọ́, mo pè nígbà àyà mi ń ṣàárẹ̀; mú mi lọ sí ibi àpáta tí ó ga jù mí lọ.

Psalms 61:2 in English

Psalms 61:2 · Berean Standard Bible

From the ends of the earth I call out to You whenever my heart is faint. Lead me to the rock that is higher than I.

Context

1Gbọ́ ẹkún mi, Ọlọ́run; tẹ́tí sí àdúrà mi. 2Láti òpin ayé wá ni èmi yóò pè ọ́, mo pè nígbà àyà mi ń ṣàárẹ̀; mú mi lọ sí ibi àpáta tí ó ga jù mí lọ. 3Nítorí ìwọ ti jẹ́ ibi ààbò mi, ilé ìṣọ́ agbára àwọn ọ̀tá. 4Mo ń lépa láti máa gbé nínú àgọ́ rẹ títí láé kí n sì rí ààbò níbi ìyẹ́ apá rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.