Saamu 48:6
Psalms 48:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹ̀rù sì bà wọ́n níbẹ̀, ìrora gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó wà nínú ìrọbí.
Psalms 48:6 in English
Psalms 48:6 · Berean Standard Bible
Trembling seized them there, anguish like a woman in labor.
Context
4Nígbà tí àwọn ọba kógun jọ pọ̀,
wọ́n jùmọ̀ ń kọjá lọ. 5Wọn rí i, bẹ́ẹ̀ ni ẹnu sì yà wọ́n,
a yọ wọ́n lẹ́nu, wọ́n yára lọ. 6Ẹ̀rù sì bà wọ́n níbẹ̀,
ìrora gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó wà nínú ìrọbí. 7Ìwọ bà wọ́n jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọkọ̀ orí omi Tarṣiṣi,
wọ́n fọ́nká láti ọwọ́ ìjì ìlà-oòrùn. 8Gẹ́gẹ́ bí a ṣe gbọ́,
bẹ́ẹ̀ ni àwa rí,
ní inú Olúwa àwọn ọmọ-ogun
ní ìlú Ọlọ́run wa,
Ọlọ́run jẹ́ kí ó wà ní abẹ́ ààbò títí láéláé. Sela.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.