Saamu 48:4
Psalms 48:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà tí àwọn ọba kógun jọ pọ̀, wọ́n jùmọ̀ ń kọjá lọ.
Psalms 48:4 in English
Psalms 48:4 · Berean Standard Bible
For behold, the kings assembled; they all advanced together.
Context
2Ó dára nínú ipò ìtẹ́ rẹ̀,
ayọ̀ gbogbo ayé,
òkè Sioni, ní ìhà àríwá
ní ìlú ọba ńlá. 3Ọlọ́run wà nínú ààbò ààfin rẹ̀;
ó fi ara rẹ̀ hàn láti jẹ́ odi alágbára. 4Nígbà tí àwọn ọba kógun jọ pọ̀,
wọ́n jùmọ̀ ń kọjá lọ. 5Wọn rí i, bẹ́ẹ̀ ni ẹnu sì yà wọ́n,
a yọ wọ́n lẹ́nu, wọ́n yára lọ. 6Ẹ̀rù sì bà wọ́n níbẹ̀,
ìrora gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó wà nínú ìrọbí.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.