Native Bible

Psalms 38:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀, ìwọ Olúwa! Ọlọ́run mi, má ṣe jìnnà sí mi.

Psalms 38:21 in English

Psalms 38:21 · Berean Standard Bible

Do not forsake me, O LORD; be not far from me, O my God.

Context

19Àwọn tí ó jẹ́ ọ̀tá mi láìnídìí pàtàkì, wọ́n lágbára púpọ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn tí ó kórìíra mi lọ́nà òdì. 20Àwọn tí wọn ń fi ibi san rere fún mi àwọn ni ọ̀tá mi nítorí pé mò ń tọ ìre lẹ́yìn. 21Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀, ìwọ Olúwa! Ọlọ́run mi, má ṣe jìnnà sí mi. 22Yára láti ràn mí lọ́wọ́, Olúwa, Olùgbàlà mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.