Native Bible

Psalms 38:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Yára láti ràn mí lọ́wọ́, Olúwa, Olùgbàlà mi.

Psalms 38:22 in English

Psalms 38:22 · Berean Standard Bible

Come quickly to help me, O Lord my Savior.

Context

20Àwọn tí wọn ń fi ibi san rere fún mi àwọn ni ọ̀tá mi nítorí pé mò ń tọ ìre lẹ́yìn. 21Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀, ìwọ Olúwa! Ọlọ́run mi, má ṣe jìnnà sí mi. 22Yára láti ràn mí lọ́wọ́, Olúwa, Olùgbàlà mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.