Native Bible

Psalms 33:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa wò láti ọ̀run wá; Ó sì rí gbogbo ìran ènìyàn.

Psalms 33:13 in English

Psalms 33:13 · Berean Standard Bible

The LORD looks down from heaven; He sees all the sons of men.

Context

11Ìgbìmọ̀ Olúwa dúró títí ayérayé, àní ìrò inú rẹ̀ láti ìrandíran ni. 12Ìbùkún ni fún orílẹ̀-èdè náà, Ọlọ́run ẹni tí Olúwa jẹ́ tirẹ̀, àti àwọn ènìyàn náà tí ó ti yàn ṣe ìní rẹ̀. 13Olúwa wò láti ọ̀run wá; Ó sì rí gbogbo ìran ènìyàn. 14Níbi tí ó ti jókòó lórí ìtẹ́ Ó wo gbogbo àwọn olùgbé ayé 15ẹni tí ó ṣe àyà wọn bákan náà, ó sì kíyèsi ìṣe wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.