Saamu 33:11
Psalms 33:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìgbìmọ̀ Olúwa dúró títí ayérayé, àní ìrò inú rẹ̀ láti ìrandíran ni.
Psalms 33:11 in English
Psalms 33:11 · Berean Standard Bible
The counsel of the LORD stands forever, the purposes of His heart to all generations.
Context
9Nítorí tí ó sọ̀rọ̀, ó sì ti rí bẹ́ẹ̀;
ó pàṣẹ ó sì dúró ṣinṣin. 10Olúwa ti mú ìmọ̀ràn àwọn orílẹ̀-èdè wá sí asán;
ó sì mú àrékérekè àwọn ènìyàn di ṣíṣákì í. 11Ìgbìmọ̀ Olúwa dúró títí ayérayé,
àní ìrò inú rẹ̀ láti ìrandíran ni. 12Ìbùkún ni fún orílẹ̀-èdè náà, Ọlọ́run ẹni tí Olúwa jẹ́ tirẹ̀,
àti àwọn ènìyàn náà tí ó ti yàn ṣe ìní rẹ̀. 13Olúwa wò láti ọ̀run wá;
Ó sì rí gbogbo ìran ènìyàn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.