Native Bible

Psalms 29:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ohùn Olúwa ń ya bí ọwọ́ iná mọ̀nà.

Psalms 29:7 in English

Psalms 29:7 · Berean Standard Bible

The voice of the LORD strikes with flames of fire.

Context

5Ohùn Olúwa fa igi kedari; Olúwa náà ló fọ́ igi kedari Lebanoni ya. 6Ó mú Lebanoni fo bí i ọmọ màlúù, àti Sirioni bí ọmọ àgbáǹréré. 7Ohùn Olúwa ń ya bí ọwọ́ iná mọ̀nà. 8Ohùn Olúwa ń mi aginjù. Olúwa mi aginjù Kadeṣi. 9Ohùn Olúwa ní ó lọ igi óákù, ó n mú abo àgbọ̀nrín bí, ó sì bọ́ igi igbó sí ìhòhò. Àti nínú tẹmpili rẹ̀ gbogbo ohùn wí pé, “Ògo!”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.