Native Bible

Psalms 29:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ohùn Olúwa fa igi kedari; Olúwa náà ló fọ́ igi kedari Lebanoni ya.

Psalms 29:5 in English

Psalms 29:5 · Berean Standard Bible

The voice of the LORD breaks the cedars; the LORD shatters the cedars of Lebanon.

Context

3Ohùn Olúwa n ré àwọn omi kọjá; Ọlọ́run ògo sán àrá, Olúwa san ara. 4Ohùn Olúwa ní agbára; ohùn Olúwa kún fún ọláńlá. 5Ohùn Olúwa fa igi kedari; Olúwa náà ló fọ́ igi kedari Lebanoni ya. 6Ó mú Lebanoni fo bí i ọmọ màlúù, àti Sirioni bí ọmọ àgbáǹréré. 7Ohùn Olúwa ń ya bí ọwọ́ iná mọ̀nà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.