Saamu 29:4
Psalms 29:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ohùn Olúwa ní agbára; ohùn Olúwa kún fún ọláńlá.
Psalms 29:4 in English
Psalms 29:4 · Berean Standard Bible
The voice of the LORD is powerful; the voice of the LORD is majestic.
Context
2Fi fún Olúwa, àní ògo orúkọ rẹ̀;
sin Olúwa nínú ẹwà ìwà mímọ́. 3Ohùn Olúwa n ré àwọn omi kọjá;
Ọlọ́run ògo sán àrá,
Olúwa san ara. 4Ohùn Olúwa ní agbára;
ohùn Olúwa kún fún ọláńlá. 5Ohùn Olúwa fa igi kedari;
Olúwa náà ló fọ́ igi kedari Lebanoni ya. 6Ó mú Lebanoni fo bí i ọmọ màlúù,
àti Sirioni bí ọmọ àgbáǹréré.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.