Native Bible

Psalms 16:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Pa mí mọ́, Ọlọ́run, nítorí nínú rẹ ni ààbò mi wà.

Psalms 16:1 in English

Psalms 16:1 · Berean Standard Bible

Preserve me, O God, for in You I take refuge.

Context

1Pa mí mọ́, Ọlọ́run, nítorí nínú rẹ ni ààbò mi wà. 2Mo sọ fún Olúwa, “Ìwọ ni Olúwa mi, lẹ́yìn rẹ èmi kò ní ìre kan.” 3Sí àwọn ènìyàn tí ó wà ní ayé, àwọn ni ológo nínú èyí tí ayọ̀ mí wà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.