Saamu 147:10
Psalms 147:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òun kò ní inú dídùn nínú agbára ẹṣin, bẹ́ẹ̀ ni Òun kò ní ayọ̀ sí ẹ̀ṣẹ̀ ọkùnrin
Psalms 147:10 in English
Psalms 147:10 · Berean Standard Bible
He does not delight in the strength of the horse; He takes no pleasure in the legpower of the man.
Context
8Ó fi ìkùùkuu bo àwọ̀ sánmọ̀
ó rọ òjò sí orílẹ̀ ayé
ó mú kí koríko hù lórí àwọn òkè 9Ó pèsè oúnjẹ fún àwọn ẹranko
àti fún àwọn ọmọ ẹyẹ ìwò ní ìgbà tí wọ́n bá ń ké. 10Òun kò ní inú dídùn nínú agbára ẹṣin,
bẹ́ẹ̀ ni Òun kò ní ayọ̀ sí ẹ̀ṣẹ̀ ọkùnrin 11Olúwa ni ayọ̀ nínú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀,
sí àwọn tí ó ní ìrètí nínú àánú rẹ̀. 12Yin Olúwa, ìwọ Jerusalẹmu;
yin Ọlọ́run rẹ, ìwọ Sioni.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.