Saamu 147:12
Psalms 147:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Yin Olúwa, ìwọ Jerusalẹmu; yin Ọlọ́run rẹ, ìwọ Sioni.
Psalms 147:12 in English
Psalms 147:12 · Berean Standard Bible
Exalt the LORD, O Jerusalem; praise your God, O Zion!
Context
10Òun kò ní inú dídùn nínú agbára ẹṣin,
bẹ́ẹ̀ ni Òun kò ní ayọ̀ sí ẹ̀ṣẹ̀ ọkùnrin 11Olúwa ni ayọ̀ nínú àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀,
sí àwọn tí ó ní ìrètí nínú àánú rẹ̀. 12Yin Olúwa, ìwọ Jerusalẹmu;
yin Ọlọ́run rẹ, ìwọ Sioni. 13Nítorí tí ó ti mú ọ̀pá ìdábùú ibodè rẹ̀ lágbára,
Òun sì ti bùkún fún àwọn ọmọ rẹ̀ nínú rẹ 14Òun jẹ́ kí àlàáfíà wà ní àwọn ẹnu ibodè rẹ̀,
òun sì fi jéró dáradára tẹ́ ọ lọ́rùn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.