Saamu 132:8
Psalms 132:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Olúwa, dìde sí ibi ìsinmi rẹ: ìwọ, àti àpótí agbára rẹ.
Psalms 132:8 in English
Psalms 132:8 · Berean Standard Bible
Arise, O LORD, to Your resting place, You and the ark of Your strength.
Context
6Kíyèsi i, àwa gbúròó rẹ̀ ni Efrata:
àwa rí i nínú oko ẹgàn náà. 7Àwa ó lọ sínú àgọ́ rẹ̀:
àwa ó máa sìn níbi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀ 8Olúwa, dìde sí ibi ìsinmi rẹ:
ìwọ, àti àpótí agbára rẹ. 9Kí a fi òdodo wọ àwọn àlùfáà rẹ:
kí àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ kí ó máa hó fún ayọ̀. 10Nítorí tí Dafidi ìránṣẹ́ rẹ̀,
má ṣe yí ojú ẹni òróró rẹ padà.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.