Native Bible

Psalms 132:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwa ó lọ sínú àgọ́ rẹ̀: àwa ó máa sìn níbi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀

Psalms 132:7 in English

Psalms 132:7 · Berean Standard Bible

Let us go to His dwelling place; let us worship at His footstool.

Context

5títí èmi ó fi rí ibi fún Olúwa, ibùjókòó fún alágbára Jakọbu. 6Kíyèsi i, àwa gbúròó rẹ̀ ni Efrata: àwa rí i nínú oko ẹgàn náà. 7Àwa ó lọ sínú àgọ́ rẹ̀: àwa ó máa sìn níbi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀ 8Olúwa, dìde sí ibi ìsinmi rẹ: ìwọ, àti àpótí agbára rẹ. 9Kí a fi òdodo wọ àwọn àlùfáà rẹ: kí àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ kí ó máa hó fún ayọ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.