Native Bible

Psalms 129:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olódodo ni Olúwa: ó ti ké okùn àwọn ènìyàn búburú kúrò.”

Psalms 129:4 in English

Psalms 129:4 · Berean Standard Bible

The LORD is righteous; He has cut me from the cords of the wicked.

Context

2“Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi wá; síbẹ̀ wọn kò tí ì borí mi. 3Àwọn awalẹ̀ walẹ̀ sí ẹ̀yìn mi: wọ́n sì la aporo wọn gígùn. 4Olódodo ni Olúwa: ó ti ké okùn àwọn ènìyàn búburú kúrò.” 5Kí gbogbo àwọn tí ó kórìíra Sioni kí ó dààmú, kí wọn kí ó sì yí ẹ̀yìn padà. 6Kí wọn kí ó dàbí koríko orí ilẹ̀ tí ó gbẹ dànù kí ó tó dàgbàsókè,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.