Native Bible

Psalms 129:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi wá; síbẹ̀ wọn kò tí ì borí mi.

Psalms 129:2 in English

Psalms 129:2 · Berean Standard Bible

many a time they have persecuted me from my youth, but they have not prevailed against me.

Context

1“Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi wá,” jẹ́ kí Israẹli kí ó wí nísinsin yìí; 2“Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi wá; síbẹ̀ wọn kò tí ì borí mi. 3Àwọn awalẹ̀ walẹ̀ sí ẹ̀yìn mi: wọ́n sì la aporo wọn gígùn. 4Olódodo ni Olúwa: ó ti ké okùn àwọn ènìyàn búburú kúrò.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.