Native Bible

Psalms 126:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa ṣe ohun ńlá fún wa; nítorí náà àwa ń yọ̀.

Psalms 126:3 in English

Psalms 126:3 · Berean Standard Bible

The LORD has done great things for us; we are filled with joy.

Context

1Nígbà tí Olúwa mú ìkólọ Sioni padà, àwa dàbí ẹni tí ó ń lá àlá. 2Nígbà náà ni ẹnu wa kún fún ẹ̀rín, àti ahọ́n wa kọ orin; nígbà náà ni wọ́n wí nínú àwọn kèfèrí pé, Olúwa ṣe ohun ńlá fún wọn. 3Olúwa ṣe ohun ńlá fún wa; nítorí náà àwa ń yọ̀. 4Olúwa mú ìkólọ wa padà, bí ìṣàn omi ní gúúsù. 5Àwọn tí ń fi omijé fún irúgbìn yóò fi ayọ̀ ka.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.