Native Bible

Psalms 126:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn tí ń fi omijé fún irúgbìn yóò fi ayọ̀ ka.

Psalms 126:5 in English

Psalms 126:5 · Berean Standard Bible

Those who sow in tears will reap with shouts of joy.

Context

3Olúwa ṣe ohun ńlá fún wa; nítorí náà àwa ń yọ̀. 4Olúwa mú ìkólọ wa padà, bí ìṣàn omi ní gúúsù. 5Àwọn tí ń fi omijé fún irúgbìn yóò fi ayọ̀ ka. 6Ẹni tí ń fi ẹkún rìn lọ, tí ó sì gbé irúgbìn lọ́wọ́, lóòtítọ́, yóò fi ayọ̀ padà wá, yóò sì ru ìtí rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.