Native Bible

Psalms 124:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olùbùkún ni Olúwa, tí kò fi wá fún wọ́n bí ohun ọdẹ fún eyín wọn.

Psalms 124:6 in English

Psalms 124:6 · Berean Standard Bible

Blessed be the LORD, who has not given us as prey to their teeth.

Context

4nígbà náà ni omi wọ̀n-ọn-nì ìbá bò wá mọ́lẹ̀, 5nígbà náà ni agbéraga omi ìbá borí ọkàn wa. 6Olùbùkún ni Olúwa, tí kò fi wá fún wọ́n bí ohun ọdẹ fún eyín wọn. 7Ọkàn wa yọ bí ẹyẹ jáde kúrò nínú okùn apẹyẹ; okùn já àwa sì yọ. 8Ìrànlọ́wọ́ wa ń bẹ ní orúkọ Olúwa, tí ó dá ọ̀run òun ayé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.