Native Bible

Psalms 124:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọkàn wa yọ bí ẹyẹ jáde kúrò nínú okùn apẹyẹ; okùn já àwa sì yọ.

Psalms 124:7 in English

Psalms 124:7 · Berean Standard Bible

We have escaped like a bird from the snare of the fowler; the net is torn, and we have slipped away.

Context

5nígbà náà ni agbéraga omi ìbá borí ọkàn wa. 6Olùbùkún ni Olúwa, tí kò fi wá fún wọ́n bí ohun ọdẹ fún eyín wọn. 7Ọkàn wa yọ bí ẹyẹ jáde kúrò nínú okùn apẹyẹ; okùn já àwa sì yọ. 8Ìrànlọ́wọ́ wa ń bẹ ní orúkọ Olúwa, tí ó dá ọ̀run òun ayé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.