Native Bible

Psalms 12:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúkúlùkù ń parọ́ fún aládùúgbò rẹ̀; ètè èké wọn ń sọ ẹ̀tàn.

Psalms 12:2 in English

Psalms 12:2 · Berean Standard Bible

They lie to one another; they speak with flattering lips and a double heart.

Context

1Ràn wá lọ́wọ́, Olúwa, nítorí ẹni ìwà-bí-Ọlọ́run kò sí mọ́; olóòtítọ́ tí pòórá kúrò láàrín àwọn ènìyàn. 2Olúkúlùkù ń parọ́ fún aládùúgbò rẹ̀; ètè èké wọn ń sọ ẹ̀tàn. 3Kí Olúwa kí ó gé ètè èké wọn àti gbogbo ahọ́n ìfọ́nnu 4tí ó wí pé, “Àwa ó borí pẹ̀lú ahọ́n wa; àwa ní ètè wa, ta ni ọ̀gá wa?”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.